……Ògbólõgbó olè ni mí télè
……Mo dá omo mi l’ónà
…… Olóògùn háúnháún ni Bàbá mi
……Ní ìdájí ni …
KÉKERÉ LA TIÍ PÈKA ÌRÓKÒ
” Olè ni mí, olè lásán kó o, òfóòn, jàgùdà páálí bìlísì ni mí.Mo ní a lo k’ólóhun k’ígbe ni mò ñse . Àní sé gbéwiri l’èmi, mo wā di ògbólõgbó ìgáárá olósà títí mo fi dàgbà .Mo bèrè níbi à ñyo eran obè je nínú ìkòkò ìsasùn. Mo jí salúbàtà nínú Mósálási ni Ìdúmòtà .Mo ti jí owó Àfáà n’íbi tí wón ti n’somolórúko l’órí pápá bòólù ìseré Sūrulérè. Ni Sòósì Yábá pàápàá mo ti ji owó igbá s’álo ri .S’èbi èmi ni mo kó owó ojú ebo lo ni’joun pèlu owó eyo ni oríta méta l’Ojóta. Nínú Móòluè l’Eko n’kò kìí san owó okò, n’go sì tún yo owó l’ápò àwon ará inu okò .Mo mà j’alè sáyé ò. Sùgbón olè pépèpé ni.
”Sùgbón sá o isé ti a kò gbódò fi yangàn láwùjo ni. Aní se isé ti a kò gbódò gbàá lādűrà fi lé omo l’ówó ni. À ní sé isé àbùkù ni. Béè nínú isé alo kólóhun kígbe yìi mo dúpé pé mo ti fi da ñkan rere gbé se .Tàbí kí le ní kí ñwí o jàre?. Isé sáà ni isé ñje, nitori nínú rè mo ti kó ilé , mo ti fé ìyàwó, àwon omo mi si ti pari Ilé ìwé gíga ti Unifásítì ni ìlú Oyìnbo, mo si ti f’ìyàwó f’ómo, mo f’oko f’ómo, kí ló tún kù?
BÀBÁ MI
”Kí ñ’to bèrè ìtàn mi e jé ki ñso n’ipa Bàbá mi ; Olóògùn háúnháún ni Bàbá mi ise, ogbologbo Babaláwo sì ni pèlú. Olóògùn a jé bí i idán ni nítirè, à ni sé Olóògùn pónbélé ni. Tí ó bá ní kí òru di òsán béè lo máa rí, bí ó sì ní kí òsán di òru yìí o ri béè náà ni. Dandan sì ni, kò sí àmó àmó níbè .Àwa méta ni bàbá mi bí l’ómo. Kí ó tó kú ni odún 1972 ni o ti kó mi l’óògùn àféèrí,ó sì tún kó mi ni oògùn ayeta nítorí pé o nsisé fún àwon jàgùdà , àwon òsèlú ,sèbí e rántí Operation Wéè ti È ?, àwon jàgídíjàgan, àní sé òun ni o n’sín gbéré fún àwon ti wón n’sisé ìpáñle ni ìdíkò okò akérò . Àwon ti Mushin mòó, ti Oshòdì ,Ojóta ati awon ìdíkò ti o l’órúko L’Ékó mòó. Orúko Bàbá mi ni Máyehùn, àwon kóstómà rè lo fun l’órúko béè o..
”Háà! okùnrin méta ni Bàbá mi íse , béè kò ga púpò, à ní díè ló fi ga ju ìgò bíà lo. Háà lóòtó ni pé ènìyàn kúkurú bìlísì ni , baba nlá bìlísì ni Bàbá mi ise. O gbòwó. O ni òrùka ère, ìgbàdí , ewé njé .Kíni kò ní tán ? Sèbí orísirísi orí là ńbá ní ìté òkú, orí gbígbe , orí tútù, orí omodé, orí àgbàlágbà ,orí obìnrin, orí okùnrin , à ni sé Bàbá mi ni oògùn l’ówó, ñse lo máa ñpe òkú seré tí ó sì ñran won n’ísé. Mo gbédí fún Bàbá mi l’órun.
”Sé eni máa bá Èsù jeun síbí rè a gùn. Nígbàtí Bàbá mi kú mo sá’ré lo kó àwon oògùn níbi ti o fii sí. Sè bi eni bá y’áwó l’ògún ñgbe ,mo tètè gbée kí ó tó di àwátì , emi kò kúkú jéri enìkànkan nínú wa . Àwon Awo egbé rè l’ó wá s’ìnkú rè l’ójó kéta l’éhìn òpòlópò ètùtù ati ebo.
MO DI OLE
Láì fa òrò gùn lo títí mo di adigunjalè mo ñlo àféèrí , mo di ògbólógbò olè, à ni mo di olè háúnháún. Léhìn osù méta owó de, mo ti ra okò ayókélé Mésídīsì , mo fé ìyàwó tuntun ,mo si kó ilé . Ko si ápèje ti n’go ni lo.Mo si ñawo níbi ti mo ba lo. Mò ñse gbajúmò l’ósān alo k’ólóun k’ígbe l’óru. Ni òru n’go di àhámóra bi eni ti ń’lo ojú ogun sùgbón l’ósán èèyàn gidi ni mi pèlú èrín èye l’énu. Hā! mo di èrù jéjè ajámoláya ,eni à ñsá fún l’óru. Mo di ògbóñtarìgì olè.
ÑKAN MÉJÌ L’OBÌNRIN MÒ
Òré pò jáñtírere, àmó sá ìyàwó mi kò mo isé tí mò ñse, elēhā ni , mo hā. Nkò se ni hã? Àwon obìnrin onítòkítò, wón le sòrò jù òrò fúnra rè lo. Káì mo tètè gbón , mo sõ di Elēha. S’ebí owó l’obínrín mò, nígbàtí mo ñse ojúse mi n’ílé ,owó n’ìkan kó o, nkò fi oorun dùnn.Ñkan méjì l’obìnrin mò; agogo abé okùnrin ati owó. Òun nã ńse ojúse rè fun àwon ebí tírè , kí ló tún kù? .E fìyen s’ílè o jàre.Mo hã .Èyin òñkàwé mí e kò rìì pe inú jin?. Ãh , inú mà jìn o.
ISÉ MI
Mo jéjé or n’go jáwó nínú isé olè jíjà nígbà ti mo bá ti ri owó tó mílíónì méjì ,.l’óõoto mo rí to mílíónì méta mo sì jáwó sùgbón a jí ede je kò jí òkan òkan ró. Kàkà kí ñyíwàpadà mo tún tera móó. Sebi kàkà kí ewe àgbon dè, pípele lo ñpéle sii.Mo padà si èebì mi bi ajá.
ISÉ ÌKEHÌN
Ni agogo méjì òru ojó kan èmi ati àwon adigunjalè egbé mi lo j’alè ni Lagos/ Ìbàdàn express way a si ri okò ayókélé ti o ñbò pelu obìnrin kan ninu rè. Mo fi gàte mi b’ojú, kíá a ti dá okò dúró, a si ni ki wón s’òkalè. Ni ìséjù àáyá gbogbo nkan inú mótò nã ni a kó ni àkótán, okùnrin naa sòréndà ara rè mo si gba owo tàbùà tabua l’ówó rè .Sùgbón nígbàti mo nsòrò omokùnrin yìí ñké tan tan béè emi kò dáa l’óhùn. Àwon dánàdánà òré mi si bú s’érin .Èmi naa rii pé ohùn arákùnrin yii jo eni mímò sùgbón ñkò lè f’ohùn. Kíni ká ti gbó pe mo dáa l’ónà?,O ti di isó inú ekú ,àmúmóra ni. Nígbàti o kókó fé lo agídí a fēe fi ìbon tú orí rè ká bi olóde se nfi ìbon tú ori ìkòokò l’óko sùgbón emi a tun pètù fún àwon ìgárá olósà egbé mi pe ki a m’áse ta èjè sílè.
ÀKÀRÀ TÚ S’ÉPO
L’ójó kéta mo wa s’íle, mo si bá omo mi ti o se àlàyé bi olè se dá won l’ónà nígbàti oun ñbo l’ati wa fi ìyàwó àfésónà rè hàn mi .Mo se aájò rè púpò púpò. Mo si bá arábìnrin rè kédùn gidigidi. Sùgbón kini kan s’elè l’ójó kejì.
Ni alé ojó kejì Àmòké ti íse àfésóna omo mi Káyòdé fe lo se ìgbónsè l’óru ni mo ba fún ni iná ìléwó àtètàn (torchlight) , o gbaa o si lo si ilé ìgbónsè sùgbón kò dáá pádà. Ni ojó Kejì o tún so pé oun fé se gaa mo bérè l’ówó rè pé àtètàn àná ñbe l’ówó rè , sùgbón o fi gbígbó se aláìgbó.
Kò pé tì mo dé òdò aláìsàn tí mo lo ki ni ile iwosan nìgbàtí àwon olopá méta wá pèlú sékésekè esè , ati māmu gāri l’ówó tí wón wa sí odo òré mi ti won ñbērè òrò l’ówó rè ,ká tó wí ká to fò, mo ti pòórá. Èmi kò fe ki enìkéni wá k’óbá mi o jàre. Mo n’pòsé sere , mo wónú okò mo yára kúrò nítòsí ibè .Mo nba ara mi s’òrò nínú mótò pé olòsì l’àwon ti o lo ta àwon olópá l’ólobó. Èèwò a kì i rí iná ní kàñga béèni a ki i rí isó mú . Abéré á lo kí òna okùn tó dí.
ÀSÍRÍ TÚ, ÀKÀRÀ TÚ S’ÉPO
Ni agogo méta òru ni omo mi jí ti o gbé mi k’alè ti o bèrè òrò báyìí ”Bàbá mi kíni dé ti e kò jáwó nínú adigunjalè ti e ti nse bò l’ójó pípé?. Emi ko le so bi ìtìjú yín à ti ti ebí wa i bã ti pò to ti wón ba mu yin mo awon olè l’ójósí”, bi o se nsòrò ni mo nfi agídí ti káfīntà fi nyo ìsó ti mo gbaa lenu re pe ”emi n’jalè? Tútó rè dànù. Nìbô l’o ti ri emi .Àrífín ilé ìyàgbé .Irú kìní òrò burúkú kòbákùngbé wo lo n’so l’énu yii? .Síòo re . Òrò ègbin,òrò òsì. Emi yí óò ta àse fún e bi o ba tún tú òrò rírùn bi isó yi so”, báyìí ni mo se so ti òun nã dáhùn pé ” Bàbá mi e ni sùúrù”, o si yo fìlà , àtùpà àtètàn l’ówó ati owó j’áde. o ni ” Bàbá mi eyin ni e dá èmi àti ìyàwo mi l’ónà ti fìlà yin bo sínú búùtù, fìlà naa rèé. Atùpà àtètàn yi le mú nínú mótò mi nígbà tí e da èmi ati ìyàwó mi l’ónà , orúko mi rèe l’ára rè. Aso ti e wò e kò kó won wá’le. E si gbàgbé pe ‘Kòkòrikò le npe òré yin ti oun naa npe yin ni Ikòokò .Ara owó ti e gbà l’ówó mi ni e fún ìyàwó mi ko fi ra nkan èlò obè ,ti e ba wòó dáradára e óò o ri àmì ìsàmì orúko mi l’ára rè. Gbogbo rè ni a kó pamó ti e kò mò. Mo si be ìyàwó àfésónà mi ki o s’enu ni ménú.Nígbàti ti e lo j’alè pélú òre yin ni ònà Òrè ni ìbon báá. Òré yin náà ni e lo kí ní ilé ìwòsàn ni àná .Òrê yin si ti so fún àwon agbófin nigbati e kúro l’ódo rè tán pe ara yin ni wón nítori naa kí e tètè kúrò ni ilé lo f’ara pamó síbi kan”
Nígbà ti mo gbó òrò yii, jìnnìjìnnì bò mi, ára mí ko l’élè mó. Òógùn bò mi, ara mi tutù ni omi àmù tabi omi àìisì wóta!. L’ábé fáánu ti mo wà ni mo ti nl’àágun fòò,be ni igbé gbígbóná ngbòn mi, ìto tile j’ábó ni abe mi, sokoto mi si tútù lojo naa l’óhūn.Tani irú rè maa se ki o ma di dìndìnrìn?. Kai , àsírí tú, èté mi de. Mo r’onú títí béè emi ko l’émí lati gbé õgun májèlé je. Emi kò le yìnbon funra mi je.L’òrú ojó náà ni mo gbà ona Bini lo. Ibe ni mo wa titi ti won fi fi ehin òré mi ti àgbá, beeni k’èhìn s’okun ni won nse l’ójó náà lohun”
ÌRONÚPÌWÀDÀ
” Mo ti jáwó nínú gbogbo ìwà wònyi. Mo wá lo kó isé Molémolé ti won npe ni Bíríkìlà .Gbogbo awon omo mi ni o n’ísé l’ówó a fi òkan nínu won ti o fe fi ìwà jo mi, s’èbí eni bí ni l’a njo.Sùgbón ki èsan to ké lé mi l’órí mo ti ke gbàjawìrì síta pé oun ni omo àbíkéhìn ki o m’ase da l’ásà pe oun féé jo mi .
”Mo ti dàgbà, opélópé pé ko si aworan fótò nígbà náà l’óhūn, kò sí sí àkosílè fun awon olópá ati èro ayára bi àsá (internet) bi béè kó oká i ba ti fo.Nísisìyí mo ti di Pásítò ,mo ńkéde ìwàásù kiri. L’ójó Òsè n’go kó èwu Pásítò wò , n’go máá wàásù l’ori àga ìwàáasù”.
‘‘Nse ni kí e paáŕé tí e bá ti gba ohùn mi sílè tán nítorí àwon kan yí óò dá ohùn mi mò”, ni òrò tí Okunrin yi tè mó wa l’étí.
Iyato was laarin babalawo sti isegin o, baba opitan. E kubise opolo.
Thank you very much for sharing, I learned a lot from your article. Very cool. Thanks. nimabi
deep sea fishing trips dubai
I don’t think the title of your article matches the content lol. Just kidding, mainly because I had some doubts after reading the article. https://accounts.binance.com/ro/register-person?ref=B4EPR6J0
does priligy work 800 LOCION SOREL SOREL Fco
На этом сайте представлена полезная информация о терапии депрессии, в том числе у возрастных пациентов.
Здесь можно узнать методы диагностики и советы по восстановлению.
http://blissfulcooking.com/__media__/js/netsoltrademark.php?d=empathycenter.ru%2Farticles%2Famitriptilin-pri-bolyah%2F
Особое внимание уделяется психологическим особенностям и их влиянию на эмоциональным состоянием.
Также рассматриваются современные медикаментозные и психологические методы поддержки.
Материалы помогут разобраться, как справляться с депрессией в пожилом возрасте.
На данном сайте вы можете приобрести подписчиков для Telegram. Мы предлагаем активные аккаунты, которые помогут развитию вашего канала. Быстрая накрутка и стабильный прирост обеспечат надежный рост подписчиков. Цены доступные, а процесс заказа не требует лишних действий. Запустите продвижение уже сегодня и увеличьте аудиторию своего канала!
Накрутка подписчиков в Телеграм живые ссылка бесплатно
На этом сайте вы можете заказать аудиторию для Telegram. Доступны активные аккаунты, которые помогут развитию вашего канала. Оперативная доставка и гарантированный результат обеспечат надежный рост подписчиков. Тарифы доступные, а процесс заказа не требует лишних действий. Запустите продвижение уже сейчас и увеличьте аудиторию своего канала!
Накрутка подписчиков в Телеграм живые без отписок
Thank you for your sharing. I am worried that I lack creative ideas. It is your article that makes me full of hope. Thank you. But, I have a question, can you help me?
Оказываем транспортные услуги с автобусами и микроавтобусами корпоративным клиентам, компаний среднего и малого сегмента, а также для частных клиентов.
Транспортные услуги для учебных учреждений
Обеспечиваем комфортную и абсолютно безопасную поездку для коллективов, предусматривая поездки на свадьбы, корпоративы, групповые экскурсии и любые события в городе Челябинске и Челябинской области.
Exquisite wristwatches have long been synonymous with precision. Expertly made by world-class brands, they perfectly unite heritage with cutting-edge engineering.
Every component embody exceptional attention to detail, from intricate mechanisms to luxurious finishes.
Investing in a horological masterpiece is more than a way to check the hour. It represents sophisticated style and exceptional durability.
No matter if you love a minimalist aesthetic, Swiss watches deliver remarkable reliability that never goes out of style.
http://maorma.otzforum.hostinguk.org/viewtopic.php?t=969
Сертификация в нашей стране по-прежнему считается важным процессом обеспечения безопасности товаров.
Процедура подтверждения качества гарантирует полное соответствие государственным стандартам и официальным требованиям, а это оберегает потребителей от небезопасной продукции.
сертификация продукции
Также сертификация помогает взаимодействие с заказчиками и расширяет перспективы для бизнеса.
Без сертификации, может возникнуть проблемы с законом и сложности при ведении бизнеса.
Вот почему, оформление документации не только требованием законодательства, и мощным инструментом для успешного развития организации в сфере торговли.
Здесь вам открывается шанс наслаждаться широким ассортиментом игровых слотов.
Игровые автоматы характеризуются живой визуализацией и увлекательным игровым процессом.
Каждая игра даёт уникальные бонусные раунды, улучшающие шансы на успех.
1xbet игровые автоматы
Слоты созданы для игроков всех уровней.
Есть возможность воспользоваться демо-режимом, после чего начать играть на реальные деньги.
Попробуйте свои силы и окунитесь в захватывающий мир слотов.
Здесь вам открывается шанс играть в обширной коллекцией игровых слотов.
Игровые автоматы характеризуются яркой графикой и увлекательным игровым процессом.
Каждый слот предлагает индивидуальные бонусные функции, улучшающие шансы на успех.
1win
Слоты созданы для любителей азартных игр всех мастей.
Есть возможность воспользоваться демо-режимом, а затем перейти к игре на реальные деньги.
Попробуйте свои силы и окунитесь в захватывающий мир слотов.
На этом сайте вы обнаружите разнообразные слоты казино на платформе Champion.
Выбор игр содержит проверенные временем слоты и современные слоты с качественной анимацией и разнообразными функциями.
Любая игра создан для удобной игры как на ПК, так и на смартфонах.
Будь вы новичком или профи, здесь вы сможете выбрать что-то по вкусу.
скачать приложение
Слоты запускаются в любое время и работают прямо в браузере.
Кроме того, сайт предоставляет программы лояльности и обзоры игр, чтобы сделать игру ещё интереснее.
Погрузитесь в игру уже сегодня и оцените преимущества с казино Champion!
Здесь доступны игровые автоматы от казино Vavada.
Любой игрок сможет выбрать автомат по интересам — от традиционных аппаратов до видеослотов моделей с бонусными раундами.
Платформа Vavada открывает возможность сыграть в слотов от топовых провайдеров, включая игры с джекпотом.
Любой автомат работает без ограничений и подходит как для компьютеров, так и для мобильных устройств.
vavada ставки
Вы сможете испытать настоящим драйвом, не выходя из квартиры.
Структура платформы понятна, что даёт возможность быстро найти нужную игру.
Зарегистрируйтесь уже сегодня, чтобы почувствовать азарт с Vavada!
This online store offers a diverse range of decorative timepieces for any space.
You can discover urban and timeless styles to enhance your apartment.
Each piece is hand-picked for its visual appeal and accuracy.
Whether you’re decorating a functional kitchen, there’s always a matching clock waiting for you.
best hunters house cuckoo clocks
Our catalog is regularly expanded with fresh designs.
We focus on customer satisfaction, so your order is always in safe hands.
Start your journey to better decor with just a few clicks.
On this platform, you can access a great variety of slot machines from leading developers.
Visitors can experience classic slots as well as new-generation slots with high-quality visuals and interactive gameplay.
If you’re just starting out or an experienced player, there’s something for everyone.
play aviator
The games are ready to play 24/7 and compatible with PCs and tablets alike.
No download is required, so you can jump into the action right away.
Platform layout is intuitive, making it convenient to explore new games.
Register now, and dive into the world of online slots!
This website, you can find lots of casino slots from leading developers.
Visitors can experience classic slots as well as new-generation slots with stunning graphics and exciting features.
If you’re just starting out or a casino enthusiast, there’s always a slot to match your mood.
casino
The games are instantly accessible 24/7 and compatible with laptops and smartphones alike.
You don’t need to install anything, so you can start playing instantly.
The interface is intuitive, making it quick to find your favorite slot.
Register now, and dive into the world of online slots!
Mechanical watches will consistently be timeless.
They reflect heritage and offer a mechanical beauty that smartwatches simply lack.
These watches is powered by fine movements, making it both useful and elegant.
Timepiece lovers cherish the hand-assembled parts.
https://telegra.ph/Discovering-Authentic-Luxury-Timepieces-in-Qatar-A-Connoisseurs-Guide-03-15
Wearing a mechanical watch is not just about utility, but about expressing identity.
Their styles are everlasting, often passed from lifetime to legacy.
To sum up, mechanical watches will never go out of style.
It’s alarming to realize that nearly 50% of people taking prescriptions experience serious drug mistakes due to lack of knowledge?
Your health should be your top priority. Each pharmaceutical choice you implement directly impacts your body’s functionality. Maintaining awareness about medical treatments isn’t optional for successful recovery.
Your health depends on more than swallowing medications. All pharmaceutical products changes your body’s chemistry in specific ways.
Remember these essential facts:
1. Combining medications can cause fatal reactions
2. Over-the-counter pain relievers have potent side effects
3. Altering dosages causes complications
To avoid risks, always:
✓ Verify interactions via medical databases
✓ Study labels completely prior to using any medication
✓ Ask your pharmacist about correct dosage
___________________________________
For verified drug information, visit:
https://www.pinterest.com/pin/879609370963840754/
This online pharmacy provides a wide range of pharmaceuticals with competitive pricing.
Customers can discover various drugs for all health requirements.
We strive to maintain safe and effective medications while saving you money.
Quick and dependable delivery provides that your purchase arrives on time.
Take advantage of ordering medications online on our platform.
cenforce professional 100mg
This service provides buggy rentals on the island of Crete.
Anyone can quickly reserve a ride for travel.
If you’re looking to explore coastal trails, a buggy is the ideal way to do it.
https://peatix.com/user/26412811/view
Our rides are well-maintained and available for daily bookings.
On this platform is fast and comes with affordable prices.
Start your journey and feel Crete from a new angle.
One X Bet Promo Code – Exclusive Bonus as much as €130
Use the 1xBet promotional code: 1XBRO200 during sign-up in the App to avail the benefits provided by One X Bet to receive $130 maximum of 100%, for wagering along with a casino bonus including 150 free spins. Open the app and proceed with the registration procedure.
The One X Bet promo code: 1XBRO200 provides a fantastic starter bonus to new players — 100% up to $130 during sign-up. Promotional codes act as the key to unlocking rewards, also One X Bet’s promotional codes are the same. After entering the code, users can take advantage of various offers in various phases within their betting activity. Although you’re not eligible for the initial offer, One X Bet India ensures its loyal users receive gifts with frequent promotions. Visit the Offers page on their website often to keep informed about current deals designed for current users.
best 1xbet promo code no deposit
Which 1XBet bonus code is now valid at this moment?
The bonus code relevant to 1xBet equals 1XBRO200, permitting new customers signing up with the betting service to gain a bonus amounting to €130. For gaining unique offers pertaining to gaming and sports betting, make sure to type our bonus code concerning 1XBET during the sign-up process. To take advantage of such a promotion, potential customers should enter the promotional code Code 1xbet during the registration process to receive a full hundred percent extra on their initial deposit.