Gbómogbómo gbé omo mi lo

 

 

…….Omo mi méjì pòórá l’ójó kan

…….Èmi kò mo orúko àwon ayálégbé náà

…….Ìyà ñlá jé mí

…..Ólópa tún fi ìyà je mí l’ójó náà l’óhūn

                            
        

     ÌBÊRÈ ÑLA: ÀWON OMÕ MI  DÀ?

           Ekún gbaragada ni abiléko   Bimbo Lékan ti i se   ìyá  olómo méjì  yi bú  sí ti o si ñgbéra sánlè l’ójó Ogbòn, osù Sere, odun 2018 (30-1-2018). Eni tí o ba  ríi yióò sàánū abiyamo  bí ó  ti se ñsokún kíkòrò  lójó nā lóhún. Nítorí náà kò ya n’ilénu nínú ìsesí áti ìhùwàsíi rè  ‘lòdò ìyá  rè àgbà ti Akòròhìn yīi ti bā .Ñse ni ó ñsáré  jáde , tí ó tún ñsare wolé ,ti  ó ńkígbe l’ohun rara ti o sì  ńbèrè pé ”Omo mì dà? omo mì dà?”. Sùgbón kò sí eni ti o le dáhùn ìbere ńla yii .

       Àwon tí kò mo ohun ti ó  dé baa rò pe wèrè ni sùgbón kò ñse wèrè o, nítorí orí rè pé  ju bí wón se ròó lo. Léèkan síi ,jìnnìjìnnì bõ, o tún bérè pe ”Àwon omo mi dà? . Ìyá je mí .Mo r’oko d’élé Dálémo. Agbón ta mí . Mo se oore dáràn. Págà!! , a tii gbó pe  odindi omo méjì põrá ninu ilé ti gbogbo wa wà yi?”.Igbe e ba mi wá omo mi ni arábìnrin yìi wa ńke tòò, ó sì ńgbéra s’áńlè bi  àgékù ejò.

    ” Ó ńta gìrì bi eni ti  àìsan gìrì mú. Ó  ńmí gúle gúle . Ó ñsúkĕ pake pake .Ó  wá  ńwò  bòò  bí  eran  Iléyá . Ojú re  le bi eni ti ó kó àtòsí. Sùgbón kò ya wèrè o, bêni kò sì kó àtòsí. Ìdāmú lo de bā. Sé  eni ti ìdāmu bá dé bá kò sí ohun tí kò le se , kò sì sí  ohun tí kò le so. Òròkórò  ni yio so, ìsokúso ni yio ma jade lenu re  bêni irànrán ni yío o ma se.

Sèbī ìwákúwá la’ñwá ohun tó sonù..        

  Ayòmídé

      Arábìnrin  yii  ñnàgà o ñwa orí tábìlì , ó tún  bèrè mólè o ńwo abé àga, o sáré wo yàrá ó ńye tìmùtìmù  orí ibùsùn wò. Sùgbón  kò ri àwon  omo  rè méjèjì níbè  .Lógán ló bá ráńtí  pé ayálégbé lo ńbá àwon omo òun seré tó  fà wón l’ówó lo tó fē ra sweet fún won .Ahh, níbo ni ó hā lo? .Ó sáré wo yàrá arábìnrin yīi  sùgbón kò si ènìyàn níbè .Ìgbóná ara mū, o sáré jáde  kò mà  ri won  mó!, Omo mi sonù sáà sàn ju omo mi nù lo. ”Bawo ni ki ñse so fún bàbá àwon omo mi méjèjì yī pé àwon omo yìí sonù. áwon ajómogbé lo se ìkà  èyi fun mi?.Omo ò mi dà? ,omo ò mi dà?. Kíni mó se? .Èé tirí? .Iná jómi , wèrèpè bò  mi, agbón ti ta mí o. Ah , ìyà ñlá  ni eléyìí.Ta ni mo sè? .Èbè la ñbe òsìkà ki ó dákun dáríjí ni”, se igbe kíké ni isé eiye, igbe ni arábìnrin yi  ñke tañtañ tan, ti o si ñfi owó lu ògiri bi Bíríkìlà se ñfi òbe ré ilé.

        Ni ojó  òni ,ogbòn ojó ,Osù Séré (January 30) ni o   pe odún mêjì  gbáko ti abiléko ti orúko nje Bímbo Lekan  ti ńwá omo méjèji ti orúko won ńjé Blessing  to wa ni omo osu mejo  ati Ayòmídé Lêkan  omo odun meji le ni osu mejo   ti di awátì ni Ojúlé Métàdínlógbòn Àdúgbõ, Òkèdógbòn  , Ò
       ÒRÒ LÉNU BIMBO
   Pélú omijé  l’ójú  òun òse ni Bimbo fi bá Akòròhìn wa Akòròhìn sòrò l’ójó nā l’óhūn, o ni ”Omo odún méjìlélógún ni mi, isé irun dídì ni mo ko,  Mo bi omo méjì ti won je omo odun méjì ati osu mejo ati àbúrò rè ti o je Omo Osù méjo. L’ójó kan ni omokùnrin kan wá  si ilé wa ni Ojúlé Métàdínlógbòn Àdúgbõ Òkèdógbòn  (27, Òkèdógbòn street) ni ìlú Òwò, lati gba yàrá kan, sùgbón ìyá mi so fun pe  a  kò  le fún okùnrin tííse àpón ní ilê .Okùnrin yìí si padà wa pèlù obìnrin ti o pe ni ìyàwó rè. A ní kí ó san   egbèrún  méjì  naira (2,000) l’ósù sùgbón ñwón bèbè fún èédégbèjo naira (1,500) l’ósù. o san owó ilé a si gbàá s’ílé. Wón san owó odún kan  a kò i tii fún won ni ìwé èrí owo sísan (receipt)  sùgbón l’ójó k’efà ni wón pòórá bí isó ti a kò ri won mó pèlú omo mi méjì.
          Arábìnrin yìí tèsíwájú nínú òrò rè , o ni  ”Ohun tí ó dùn  mí  jù ni pé a kò kò tíì fun wón ni receipt .L’ójó tí wón jí omo gbé yìí arábìnrin ti o p’era rè ni ìyàwó okùnrin yiì gbé omo mi tí o ñsúnkun .Ó si ñba mi d’irun fún èkéjì níwòn ìgbàtí o so pé isé irun dídì ni oun yàn láàyo. l’éhìn èyí o ni oun fé ló ra sweet fun won.Èmi sì ñfõ aso l’ehìnkùnle.
Obìnrin náà tè  síwájú o ni ”Nígbàti mo parí aso fífò mo wá àwon omo mi tì sùgbón ti a wo yàrá obìnrin yìi àpo Ghána Must Go nìkan ni a bá n’íbè , nínú rè ni a ri bébà tií wón ti gé wélé wélé nínú re .
        KO SI ÀWÒRAN ÀWON OMO
    Nígbà tí Akòròhìn wa Táíwò Abíódún bérè àwòrán (photographs) àwon omo méjèjì, nse ni obìnrin yìí ñwò pàkò pàkò bí orí eran ti o so pe òun kò ni àwòran won l’ówó àfi èyí kékeré n’ígbàtí ti o wà ni omo osù méjì’
Ñse ni wón ñsó obìnrin yìí l’ówó l’ésè bí eni ti o ni ode orí n’ígbàtí Oníròhìn wa báa l’ódo ìyá rè àgbà l’ójó náà l’óhūn.
   Ìròhìn tó tè wá l’ówó nīi pé l’áti ìgbà yen   à  kò gbúrõ wípé wón rii  àwon omo mêjì yi ì rárá.
E kò háà ri n’kan bí? .E wáíye obìnrin abiyamo l’óde.
Àdúrà tán n’ílé aládúrà , olópã na ñké tantan ,beni ará àdúgbò ñ’logun .Ìgbàkigbà tí obìnrin yìí ba ji l’órū l’áti fún omo rè l’ómú  ni yíõ tó ráñtí wípé awon omo òun méjiì ti di àwátì.
Awon omo wa kò ni  di àwátì o. E se àmín kí e fi owó àdúrà b’ójú , kí e si fi owo àdúrà s’owó ráñsé si òùnkòwé yìí.  À ní  títí di bí a se ñkòwé yī a kò  gbó nkànkan n’ipa àwon omo méjèjì yīi o.
Sùgbón bí a se ñko ìròhìn yìí Obìnrin yí sì wà l’áíyé ó sì wà l’áàìyè rè o. L’óotóo omo mi kú sàn ju omo mi nù lo bēe si ni   A kò mo ohun Olóun yí oò se  ko je ká b’ínú kú.

NB

E f’arabalè l’á’ti gbó òrò y’oku l’enu arabinrin yi ninu fidio yii

 

Ara pípé ni mo fi kúrò l’America,mo padà pèlú àbò ara

 

       

  Háà ! e wo èjè lára Obájolú

   ….Dérébà  okò  nā pápá b’ora

  ……. Olówò of Òwò,Olíyèré of Ìyèré, Atúlúse Rótìmí Ìbídàpò s’ājò

    …….. Wón rān mi n’íbi méédógún (15stiches)

   ……..Ìyàwó mi bú s’ékún gbaragada

……..Nwón rán etí, ìpempé ojú ati èrèké mi

Obájolú fi èdè abínibí rè (Òwò)  bá akòròhìn wa Táíwò Abíódún sòrò

 NÍTORÍ ÌKÚNLÈ ABIYAMO Õ

Èjè ńya l’órí , l’ójú, l’étí àti l’érèkē!. Nítorí ìkúnlè abiyamo ò ò! . E wo bí aso funfun báláú ti di pupa l’ówó èjè. Ó dàbí ìgbà tí àwon alápatà bá ńgé  eran mààlúù  ní àtéńdà. Okò ayókélé ti di okò Owódé Onírin  níbi tí wón ti  ńta okò tí wón ti ńgé wélé wélé bíi télò (tailor) se ńgé aso .E wo bí  iwájú ati èhìn okò ti di búrédì  tí a fi owó  tè.

”Yépàrìpà kí ló n’selè? . Kí l’ódé? .Tani mo sè ?.  Sé  èèwò ni kí a tún wá be ilé wò? . Kí ló burú  l’áti wá bá won se ayeye ní ìlú tí a ti bí mi? . Sé isé  owó  àwon òtá ni tàbí àwon  ayé?. Lõtó ayé kò f’éni f’órò  à fi orí eni”, ni igbe tí arákùnrin  Sámúélì Olúwáfémi Obájolú ńké tan tan ti ānú rè sì ńse ènìyàn.

                                              Ó mà se ò! E wo isé owó Dérébà

      OJÓ BURÚKÚ ÈSÙ GBOMI MU

Ojó burúkú èsù gb’omi mu ni ojó tí arákùnrin   Sámúélì Olúwáfémi Obájolú ti ó ti lo ogbòn odún ni Maryland , America  ti o sì tún jé igbá kejì Asojú Omo ìlú Òwò ni gbogbo ilè Amerika,World Council of  Òwò Association (WOCOA) fi ara pa nínú ìjàmbá okò ayókélé rè níbi ti ó páàkì rè  si tí ó sì ńdúró de òré rè.

Ìsèlè burúkú yìì selè ní  ìlú  Òwò, ni ìpínlè  Oñdó  ti a  fi orí okùnrin yii   s’olè sí . Okùnrin arewà yii ńbò láti ibi tí o ti lo bá won se ayeye  ojó àìsùn èye  ìkéhìn fun ìyàwó bàbá rè tí ó papò dà  l’ójó bi mélo kan séhìn.

 Níbi ti arákùnrin Obájolú yìí páàkì  okò  rè si ti o  jókòó sínú  rè  tí o  ńdúró de òré rè ki wón jo padà sí ilé ni okò ayókélé kan ti ńsáré  ikú  bò ti  k’olu okò arákùnrin yìí lójijì láti èhìn. Nse ni Obájolú fi orí so díńgí iwájú  tí díńgí èhìn okò náà tún fo lùú, báyìí ni èjè se we arákùnrin Obájolú yìí  bí eni tí o sèsè fi omi wè ni balùwè ni. Èrèké, ori, etí àti ìpémpé ojú re fà ya, èjè sì  bòõ títí tí aso àlà funfun ti o wò di pupa nitori àgbàrá èjè ti o ñsàn l’órí rè yìí.

 Yéè  gbèsè ńlá rě

ÌKÀ  AWAKÒ   SÁ LO

Omo aráíyé mà ní ìkà  oo, ìkà sì ni omo aráíyé. Kàkà kí arákùnrin awakò   òdaràn  yíí  dúró wo àláfíà okùnrin tí ó k’olù  yìí  ñse ni o fi okò  ayókélé rè sílè  ti o júbà ehoro .Ó  fi esè fée.  Ìgbé ã fé ewé. Ìsèlè yìí selè ni agogo méwàá k’ojá ìséjú méédógún alé  ojó Boxing Day., Osù Òpe, Odún Kérésìmesì ti àwon elésìn Krìsténì l’ódún tó k’ojá.

Sùgbón Obájolú hùwà akoni , pèlú  ìróra àti èmí ti o kù  nínú  rè ni o fi fóònù àgbélówó  pe àwon dókítà Federal Medical Center (FMC) ,ó gbìyànjú nínú àgbàrá èjè tí ñsàn l’órí  rè  l’áti pe àwon Dókítà tí ó ti mò ni ilé ìwòsàn yíí ki wón jòwó gba òun  bi bàbá ti ńgba omo rè.

      E wo ilà òsángangan  l’érèké Obájolú  ,èjè ñtú yā l’étí

Nígbàtí Akòròhìn wa fi òrò jomitoro òrò l’énu Okùnrin ti ìjàmbá mótò se  yìí  nā ni Ilè Améríkà, e gbó  àlàyé tí ó se. 

ENU ONÍKÀN LA TI ŃGBÓ PÒÓÚN

Tóò,  ńwón ni enu oníkàn lati ńgbó pòóún, e jé ká  gbó  òrò lati enu Obájolú :   ”Lati Ìlú  Òyìnbó ,Améríkà ni mo ti dé, èmi ni igbá Kejì  (Vice President ) World Council of Òwò Association (WOCOA) Atúlúse asojú gbogbo omo  Òwò ti o wa ni ilè aláwò  funfun, America ni gbogbo àgbáláiyé  . Mo  wá si ìlú mi, Òwò fun ìdí pàtàkì méta , èkíní  láti wáá  bá  Oba Aláíyélúwà Gbádégesin Ajíbádé Ogúnoyè Ìkéta wa se ayeye òpá àse ti Gómìnà ìpínlè Ondó Arákùnrin  Rótìmí Akérédolú fĕ fúnn pe o ti di Oba Aláse  ni Ojó Kerìnlá  Ojó Àbáméta ti a ńpè ni Sátidé ni Osu Òpe. Ìdí èkéjì ni ti ìyãlé  ìyá mi ti a ńse ayeye  òkú re ni Ojó kerìndínlógbòn ati ojó ketàdínlógbòn Ojó Etì ati Àbáméta , ìkéta ni ti òré  mi Oloye Fúnsó Ògúnlànà  ti o  ńse ayeye márùndílógbòn odún ti a npe ni Silver Jubilee  ti òun ati ìyàwó rè ti se ìgbéyàwó ati ojó ìbí ìyàwó rè ti o pe àádóta odún .Ó  se ni l’áánú wípé  emi kò lè lo si ibi ayeye méji yi mó àfi ti ayeye ibi ti a ti fún Oba wa Olówò  ti ìlú Òwò  ni òpá àse nìkan ni mo lo. Se rírò ni tènìyàn, síse ni t’Olórun Oba!. 

     

Ààre Atúlúse Rótìmí Ìbídàpò ati Obájólú ki ìsèlè ìjàmbá okò nā  tó selè

”Nípa ti ìpalára ti mo ní, l’ójijì ni mo gbó gbã ti okò ayókéle  kan k’olu okò ayókélé ti emi wà ninu rè láti èhìn nígbatí mo ñbo lati ibi aìsùn ayeye ìkéhìn ìyàwó bàbá mi ti èmi ati òré mi  Akin Oládiméjì ti o ñwà mi kiri.

Obájolú ati Aláíyélúwà Olówò ti ìlú Òwò  ki  ìsèlè ìjàmbá okò tó s’elè

  ALÁÁNÚ ARÁ SAMÁRÍÀ SEMÍ LÕRE

     Pèlú bí wón ti ni ènìyàn búburú pò tó, ñjé é mò pe ènìyàn rere háà tún wà bí?. Níbi tí Obájolú ti npe òré  rè dókítà ni arákùnrin kan ti ñje Ògúnmóláwa télè (now Olúwámóláwá) sáré tete  wā ba Obájolú lati gbee lo si ilé ìwòsàn,  béèni  ñwón  ñpèé l’ótún àti  l’ósì ti won  nse aájò rè, o wa dàbí Àre ñwè l’ódò t’omodé t’àgbà  ñyowó ose nwípé t’èmi ni o gbà,t’èmi ni o mú. Láì fa órò gùn lo wón gbé mi d’élé ìwòsàn , níbè ni mo rí  awon ògbóñtarìgì Dókítà méta ti won ńdu èmi mi. Hã Obájolú ko gbódò ku ni igbe ti won ñké lénu.

Yěpàrìpà okò ti di  ti Owódé Onírin

    RERE LÓ PÉ

        “Njé e mò pé òkúta ti a ba jù síwájú a ó ò  tún bãa, rere ló pé ìkà kò  pé. Ni òpòlópò ìgbà ni èmi àti àwon èèyàn mi ni ilè America ńkó oògùn, ohun èlò lórísirísi wá si ile ìwòsàn yî nítorí awon ènìyàn wa tí won kò ni ànfàní lati wa gba iwòsàn ni ìlú  America. Ni osù Kérin,( Osu Igbe )  odún tó  k’ojá ni gbogbo àwa ti a wà ni ìlú America parapò ti a kó àwon aláwòfunfun dókítà onísé abe, Nôsi ati  ohun èlòo ati òpòlópò egbòogi wá si ile ìwòsàn yi. Mo rántí Dókítà Oláyíwolá Olágbègí ati  Ogbéni Pharmacist Ògúnmóláwá ni ilu St. Louis ,Missourri , ati àwon béèbéè ti wón  wá pèlú. Gbogbo àwon dókítà wonyi : Liasu Ahmed, Fasiroti, Oyemolade Ibrahim Taoheed ni wón t’éwó gbàá nígbà  nāa, wón dá mi mò dáradára .Nwón gbé mi lo si tíátà ,iyàrá ti wón ti ńse isé abe  (theatre) wón si rán etí , ìpémpé ojú  ati èrèké mi, èyí so mi di òkolà l’érèké l’ósángagan. ”

  Pèlú ìbànújé okàn  ni  okùnrin náà tèsíwájú ninu òrò rè, o  ni “Nwon kò gba owó l’ówó mi rárá, òfé ni won t’ójú mi ní ilé ìwòsàn FMC .Mo si lo ojó mérin gbáko ni ilé ìwosàn  yii. Sùgbón sá o l’ójó kejì  ìselè yi ,nse ni  nwon  tún fi okò pàjáwìrì (Ambulance)  asáré tete  bi àsá ti won fi ñgbe alaìsàn gbé mi lo si Àkúré lati se MRI , awòrán  orùn mi ati gbogbo èyà ara mi fún àyèwò fínnífínní bóyá a kìí mò ohun ti o ti s’elè s’inú àgó ara mi. Mo san  egbèrún l’ónà ogóta náírà(60,000 naira).

      .

Ewà rèé, sùgbón ìyàwó mbe n’ílé o èyin abéléja yán

Mo kúrò n’ílé iwòsàn l’ójó  kerin , sùgbón nígbà tí mo wà níbè  Oba wa Aláyélúwà Oba Gbádégesin Ajíbádé Ògúnoyè III, Oba Omótúndé Adáko (Olíyèré of Ìyèré), Olóyè Atúlúse ti ilu Òwò, Rótìmí Ìbídàpò ati awon òré  ati ará ilé oun ojúlùmò wa bè  mí  wò. Awon ti kò le wa  fi ipè ráñsé.

   ÈRÒ MI L’ÁTI TÚ ILÉ ÌWÒSÀN SE SÍI

”Nígbàtí mo wà  n’ílé  ìwòsàn mo rii pe o ku díè kã to n’ípa ohun èlò irinsé ilé ìwòsàn yìí mo si pinú pé  ńgô gbìyànjú lati ra orísirísi ohun èlò si ibè . Emi ni o se l’oni tani a mò ti o  máa kàn lóla?.Ňjé mo tilè là  àlá pé èmi nã yio je àñfàní gbogbo ohun èlò ti a kó s’ílé ìwòsàn  yìí  ní kíákíá?. E è wo isé Olórun Oba bí? .Oba àwámáridi .

   Háà,  ìkà ní  Dereba yii

EMI RÈÉ L’ÓWÓ OKO ÀÁRÒ

”Èmi rèé o l’ówó oko àárò. Mo fi ara pípé wá sí  ilé mo  sì  gun kèké aláàbò  ara  padà  si ìlú Òyìnbó , èé ti jé? . Nígbàtí mo dé pápá  ìdíkò òfurufú ti Múrítàlá  Mohamed ni ìlú Èkó ni wón fún mi ni Kèké aláàbò ara (wheelchair) lati fi se àtègùn sínū bààlúù . Nígbàtí mo tún dé ìlú America kèké kanã ni mo tun lò ni pápá ìdíkò   òfurufú won. Gbogbo won lo ñkí mi kãbò, mo kú orí ire.

“Nígbàtí  ìyàwó mi gbó, igbe ńlá lo bú si, ó si bú s’ékún gbaragada bī bèbí béèni o si ńgbàdúrà fún mi kíkan kíkan pèlú òpòlópò  ãwè. Àwon omo mi kò tètè mo ohun tó s’elè sí mi.

IYÁN OGÚN ODÚN

”O jé ohun ìbànúje àti ìyàlénu fún mi l’ati ríi pé omokùnrin dérébà ti o w’akò ijàmbá yii  fi pápá bora. Emi kò gbúró rè  títí mo fi padà si ìlú  America .Háà! o ti gbàgbé wípé iyán ogún odún a  máa  ńjó ni l’ówó join join. Omodé bú igi ìrókò o nbu ojú w’èhìn, sé  òòjó  ló  ń’wó pani ni?. Bi mo se ń’sòrò yii okò ayókélé mi náà wà ni àgó olópá. Mo gbó pé àwon ará ilé okùnrin ti o fi okò k’olù mi yii ńwá bèbè l’ódò àwon  ènìyàn mi pe omo àwon kò ńmu otí àti pé Ààfáà Mùsùlùmí gidi ni .

”Sùgbón kíni ká ti pe irú èyí?. Efun ni  tàbí  èdì?. Kí awakò máa sáré máìlì ogórin si ogórún ni ìgboro ìlú? .Ìkà ènìyàn rèé o, t’àbí kíni kí nso?” .

 

 

 

Behold Akinrogun of Egan the Warrior!

 

………I arrested 20 robbers one night

.……Sango is now peaceful

……The real meaning of Otta

…….I am a graduate of OAU

Akinrogun 1

THE MAN

      At home he  is gentle like a lamb but he  is as brave as a lion  and as strong as an ox when there is a cause for it.  He is a man of few words. Yes, he  looks calm and peaceful and almost monastic. But don’t underrate him. Although his look could melt a woman’s heart while  his appearance and soft voice  could make Miss World   fall yakata for him and say ‘I do’ . Still  he is not that simple and easy.

     But wait, there is more to this man than his features. He is a generalissimo.When the light- complexioned man removed his shirt and showed incisions from his head  to toes then nobody will tell you  to fear  him  as  you will not only pee  in your pants but will also doff your cap for him and give him more respect and shout Shon Sir!”. Yes, the fear of Akinrogun is the beginning of wisdom to  criminals.

       Call him a warrior . Label him a Generalissimo.Tag  him a local liberator or ”saviour” , the Obafemi  Awolowo  University graduate  of  Home Economics is ready to give you  Egba stories  without opening a book!. Despite his simplicity he talks tough, he is an Historian as he knows the Awori, Egba History like the palm of my hand .Known and respected in Sango area of Ogun State. This  is Chief Adeniji Olatoye Ismaila, the Akinrogun of Egan .

       Here is a man who acts his name , Akinrogun ( Akin who sees war). He  is a warrior whether local or state a warrior is a warrior .He rescued  his village from being plundered by the so called ‘enemies ‘. Again here you  meet Chief Adeniji Olatoye Ismaila  .

He introduced himself  ”My names are Chief Adeniji Olatoye Ismaila the Akinrogun of Egan.  I  am 48years old (now 50) I became Akinrogun  of Egan  in 2007 .

Akinrogun 2

I BROUGHT PEACE TO SANGO

      According to Akinrogun, he was born and raised in Abeokuta ( Totoro) , and his  village is Lapeleke .  He introduced himself  ”I’m a painter and a designer  by profession .When  I came to  purchase a land  here in the year 2002   a group of people (names withheld) started disturbing  us . We all came to this town not knowing that it is the land of   our forefathers, but when these people  (names withheld)  continued  disturbing us  then in 2006 we went to Owu to inform our leaders that we were facing war with the …….( names withheld)  they then implored us to dig into history and confirm that we the Owus owned the land and should know what to do . Baale Idowu Jacob who was the leader then tried his best for the community .I went to them and   introduced myself that I am from Ololo household family in Abeokuta , and also Lapeleke

Incisions all over my body

Akinrogun went down memory lane to remind us the war he fought, he said  ”it was no war , no peace ”. The  two oppositions fought with all manners of instruments. Akinrogun said “the  fight between the Owu and….. (names withheld) was serious then, our opponents  shot a lot of bullets and used juju, but we overcame them , and that was in the year 2007. We  too fought with juju, guns, and  we advised  our people to go home and research on  what it takes to fight a war. We told them  to  go and reinforce spiritually from their father’s families whoever has , in the end our opponent’s  king  fled , he is dead now”.  Akinrogun boasted  ”later when we became Chiefs we were relieved and peace  has been reigning since  then.”

He claims that  the ….. ( opponents) were  deceiving people that they are offering sacrifices but disturbing them , he said “they pretended to be offering sacrifices but used it to foment  trouble , thank God that Egan town and Igbo Olowu are peaceful today , if we want to  offer any sacrifice or rituals we do it in the midnight when everybody had returned and retired home! , and if any of the Bale is dead and there is need to offer sacrifice and rituals we do it in the midnight so as not to disturb others ”

MEANING OF AKINROGUN

Asked whether he has juju, he exclaimed ”don’t you know the meaning of Akinrogun? Whoever  takes the title of Akinrogun must have juju, money and connections”, he stated.

The  Warrior said he has only one wife, and says he does not unnecessarily get annoyed , he said ” position, power and money are powerful tools that push one but one has to be careful in life for him to  live long.”

Does his wife fears  him?, he replied ” Yes, she has to because of all my activities”, he responded.

 I ARRESTED ROBBERS IN THE DEAD OF THE NIGHT

He recalled an incident some years back ” An incident happened in a midnight and   I was called   to come to their rescue.I was in my Boxer pant only and was not prepared but  I know there is God in His highest coupled with our innocent  and sincerity for we did not betray anybody , and God assisted us , we caught the robbers  and handed them over to the police . They wounded some people, they used cutlass on me but it had no effect on me.

”They were  about 16 armed robbers that   invaded our place. I wore my boxer , called my colleagues and went after them . With some of my members  we went out to  face them. I thank God that we eventually arrested them after a lot of exchanged of bullets .They shot me several times but their bullets had no impact on me. We arrested the robbers in the end  , infact it was a gallant fight” .

Akinrogun 2

WHO IS AFRAID OF AKINROGUN?

Asked whether he is not feared with the incisions and manner of arresting criminals, he replied “My wife fears me , my friends too are afraid of me.You know position, status, money and juju could push someone but I have to be careful  if I want to grow old”.

STORY OF OTTA

On  the story of Egba , he said he is rich in the Egba’s  History because  he is from  a royal house.  He started:

”Many, many years ago  when the Dahomey waged  war and wanted to take the Yorubas as slaves   the Egbas resisted and fought back. The Egbas  came from Igbalefa, those called Igbalefa are Ake, Gbagura, Oshinle, Owu  and Keeta . They all came together fight the Dahomey , they fought the war for years  and killed the King of Dahomey in Oke Ore , that is why till today we have  the powerful warriors, babalawos and powerful men are there till today. And that is why they observe ‘Ose’ every Monday  there. The meaning of ‘Ose’ is that the Babalawos would gather together there to meet the gods  that assisted them to kill  and  beheaded the Dahomey King . After the war,the Warriors left . Who is Awori? There is nothing like Awori. Who is Otta? there is nothing like Otta . It is  the  people from Kogi state, Oyo and  and other towns  that would come here  to trade that is buy and sell…..the Kogi would say    ” A ti n’lo ta, a ti n’lo ta” (we are going to sell or trade). Go and read the History of  Yoruba, it is  in their archives for you to read. It was when the Egbas gave the Aworis some space or piece of land ..They were given 500 meters in Sango and it is from that 500 meters in Sango  that we have the local government  of Otta . All Iyana Iyesi, and Ilobi etc   are owned by the Egbas. But now we thank God  the Egbas rose up to claim their right..

”We have Oba Igbalefa in Iyana Ilogbo, The Owus  have reclaimed Sango, half of Sango belongs to Otta and half of Iyana Iyesi belongs to Otta , and Awori also have theirs because it was Egbas that gave them to be farming there , and when they become old and have children they were no longer customary tenant , they were left there to be enjoying their lives”.

Asked where he got all these stories , but the man said ”thank you , if a child does  not witness event or history  he would  hear tales or meet the story teller, which is the father of  history  ( Bi omode ko ba ba itan , a ba aroba, aroba si ni baba itan) because I was very close to the elders and wise old men who are historians and Griots. It is a long story but take it like that.My father was not a king but he was the  father of a king. I am from a royal family.”

How I slept with my mother

He worked in one of the defunct  first generation Banks and became a  Bank Manager of a Branch  at  the age of 30  for ten years. But for  thirty years he has been living from hand to mouth. In his hey days he was brilliant and was known for his love for Algebra and Geometry  . Today he is 72years old and his head is full of grey hair but he is  suffering . When he met a powerful  Prophet who asked  him to confess  the  sin NOT CRIME  he once committed against his mother .

He then gave a mind -blowing confession that could make one go mad!.

He said  ” BoN  please write your story but DON’T EVER,  I repeat DON’T EVER  mention my name for I will not only CURSE but also SUE you . This condition was met by this reporter.

      The old man paused and  looked around as if he was being pursued . He smiled again and  soliloquized “I made some blunders. I  made some blunders. I just need to beg God for forgiveness but it was not my  fault , it was the devil’s handiwork.

”Do you remember the man that used to have carnal knowledge with his mother on our street when we were young?. Do you  remember how we used to point at him while going on the streets? . By then many thought he was  mad  ,  now I know that he was not mad. I remember that in villages many knew what was happening  but in the cities hardly will they  know especially those living in flats.  Now let me tell you my own story.

“When I was very young and naive I met a friend who told me how he was making love with his mother . I said “impossible”. He smiled   and said ” it is simple and easy” .  This thought  flooded my mind while growing up. Whenever my mother and sisters were having their bath I would be peeping  through the gaps  in the  thatched   leaves /palm fronds in the village.  Later we all moved to  another town  where my brother was living with his wife who was expecting  a baby . I had already become  peeping  Tom, as I peeped through the key hole and I always watched my brother’s wife having bath. I extended it to my mother  too .

“One day I met my mother  who carelessly  slept off in her room  half -naked with a lubricant  and vibrator. I later discovered that she was always alone  in her room while the  television would be switched on,  but no voice for she would turn the volume down . I have caught her red -handed many times with   a bottle of  local gin, kainkain , later  I took it as habit buying  bottles of the illicit gin for her always .

“One evening she was drunk  and senselessly   allowed me to   watch the adult film together in her room . Before I knew what was happening she had  grabbed my John Thomas   which had been dangling and moving its head like agama agama lizard.  And that was all I could remember  until I was lost in  her  deep forest as she was moaning begging me not to leave. That was how  I had my  first experience and  I started sleeping with my mother without the knowledge of my brother and his wife for five years .

”I   started sleeping in her room and nobody ever thought of what we were doing. When I was working  as auxiliary  teacher  I would rush home  at  break time to have a quickie with her. I found it interesting and fun,never a sin!. Meanwhile my brother and his wife thought I was a serious person who did not like women or sex for not bringing ladies home. After my brother’s wife gave birth , my mother still stayed.

”Our sexual escapades got to its climax when I rented a room  apartment and was living alone. My brother implored me to  stay in order   to have enough savings before I move but because of the free sex I was having I refused. My mother would come and spend days  with me in the name of coming to say hello to me yet my brother was ignorant of everything.

”One  day my landlady caught us red-handed while we were doing  it in my small living room , we forgot to lock the door from behind.  She  had wanted to give me the receipt of the house rent I paid  for the previous day and met me on top of my mother  jerking her while she  was screaming  and moaning at the same time  wriggling  her waist but  I couldn’t stop, you know when you are in Cloud 9 and your brain is charged cum your blood running in your veins .We continued for we were lost in the lust .My eyes bulged out as if trying to burst.Yes, the kainkain I took was working!.

”However, the landlady who was an elderly and wise woman called me and my mother separately and talked to us to stop the act. She even called me secretly and asked whether I was doing it for ritual purpose and I said ”no”. But as the devil would have it , we continued until she reported me to my older brother who cried                    ‘ abomination’.  He  threatened to report me to my father who was still alive in the village .

”We stopped doing it .

”My mother became sick .She was taken to the hospital where a doctor said she was having fibroid that made her to be bleeding.By then she was 55 years of age and she did not go back to the village because my father had other wives.

”Her cries and bleeding  from the fibroid pain  was too much .At the hospital the doctor said it  could be fibroid. But when she went to another doctor, a scan was done and  she was told that  she was  four  months  pregnant with twin babies as the scan showed there was no fibroid but babies!.

”We shamefully told my brother who said she should abort it . But the doctor said the abortion might lead to her untimely death.

”My mother begged to go and rent another house in order to have the baby for my brother  and I were the only children  she had . She  refused to abort the babies  and was attending   antenatal Clinic.  These twin  babies were delivered in 1980. This January they would be 40years old. They read good and lucrative  Courses ;Medicine and Mechanical Engineering  and came out in flying colours and  are graduates of …. from the University of… they have good job but with unstable lives!. They are not married  .. They are known and popular . Each time they ask of their mother I would not tell them the true story.

”Each time I looked at the twins  who are males I feel ashamed  while my mother always argued and consoled herself that that is how God wanted it , and if He had not wanted it the babies would not have stayed. She would stupidly and foolishly be referring to the  Bible and be saying ‘‘oju ri iru re ri” (Meaning  it is not a new thing) what a shameless mother I have!.  I could not marry for anytime I proposed to ladies they would tell me their spirit rejected me.

For several years I have not been doing any tangible thing .Few years ago my twins came to ask me some pertinent questions on why their lives were rough and not making it .They said a strong Prophet told them I committed an abomination. Apart from that they asked me to confess the relationship between me and their late mother.I knew they must have been told.

”I have told the Prophet the naked truth and the whole story of my life. He asked me to  call elderly people in the family  and beg the these children.”

Confession of a dying police officer

 The old man was  barking like a dog while narrating  his story . He however begged that the story should not be published until after his demise. He died in  October  last year and we are publishing his heart -wrenching story that would send shivers into your spines.

For six months  the Muslim Cleric  Seriki  Karoose  Sokoto (not real names)Sokoto could not go out  as his children locked him up in a room. Reason: maggots were coming out from his body (from head to toe) and the whole house was wafted with foul  odour.   During  the day Pa Sokoto  would be barking like a dog while in  the night  he would be screaming  and begging the unseen hands flogging him to forgive  him.

         MY REAL IDENTITY
The Muslim Cleric  Seriki  Karoose  Sokoto (not real names) insisted that his  two grown- up children must not  join the Police Force. In spite  of his disapproval ,one  of them secretly enlisted. On his deathbed he called his two children; Azeez and Adamu and said ”  it is high time I let  you know the truth about my identity. Do you know why I don’t have a cellphone and don’t appear in the  social media?. I don’t belong to this  land , my real  names are Aseyiowuu  Esanake (not real names)  and I was a Christian by birth but not a Muslim  .My parents were staunch  Christians”.  

 

WHY I JOINED THE POLICE FORCE

” I finished my secondary school at Saretete Village,  I worked as a temporary teacher and later joined the Police Force in 1977 at the age of 30  after  a rigorous  training  from  the popular  Police College . It was a one -year training where they  shaved our  heads  and were given a pair of shorts and Singlets  . After the training I was posted to Calabar  and ‘armed’ with my baton and torchlight the first  compulsory two tools  of a policeman  . I  later   worked my transfer back to Lagos where I had lived for years and a  lucrative city  for the   kind of  my  profession . My dream to become a police officer   fulfilled  .I joined the Police Force because of the uniform which was always starched and the respect they  give them  cum  the  fear instilled in the civilians’ hearts about them .In a nutshell a police officer was  like a tin god in those days.

“When I rose to the rank of  an Inspector , and  they added the  prefix ”Inspector”, to my name and started calling me  Oga Inspector  and I felt happy  and great. Inspector? .I  dreamt that one day I would become the Inspector General of  the  Police  Force. Each time I glanced at the big photo frames of the past IGs , I would smile , and say to myself  that one day my own picture would  be hung there and I would be fulfilled.

                                               

                   BoN’s Adventure

”As a recruit then my salary was 80 Naira per month.The money though was small but I was satisfied .I always took my uniform to the dry cleaner  which was always well -starched and well- ironed with the ropes attracting  many. My shoe? ,always shinning . In fact I go about with a brush and polish to do justice to  my shoe when dusty .I had a wife and two children at the age of 33.

I HATED BRIBE

”Lest I forget to remind you that  I  hated corruption,  whenever  my colleagues collected money from the civilians  who had civil or  criminal cases  I always rejected and used to preach to  them that it’s evil and that they would be visitors  in  hell fire.

”One day, before I left home my wife fell ill, my two children were thrown out of school for non  payment of tuition fees. I went to work hoping to borrow money from my boss. But my boss said he had nothing on  him. Full of sadness ,when I returned  home I found my wife stiff . She was stone  dead! .

”I broke down and wept .Her ailment was  malaria cum hypertension but all the medicines the doctor prescribed for her  were not bought. No money!.

”After her death my friends and family members who I once begged to borrow me money came with stupid  surprises to assist me for the burial and life continued .

”One year after my salary was increased  to 135 Naira per month. But after paying for house rent, children’s needs and other things I had nothing on me and in church I heard how the preachers rebuke  givers and takers of bribe as they were compared with the  Biblical  Zacheaus the  tax collector.

”One day , Ayo my son was sick, he had malaria while his older brother , Paul  had  appendicitis, the doctor asked us to come for the surgery which would cost  30naira , but instead I started applying palm oil as soothing balm while  he was groaning in pains and rolling on the ground . Later he could not bear it .I appealed to many to assist but none came to   my aid.

I MADE A ‘U’ TURN

”In the evening I went out  with my torchlight , baton and gun and  mounted an illegal check point .In a nutshell I realized 50 Naira that  evening when my salary was 135 Naira per month! 

”I quickly went back home and took Ayo and Paul  to the Hospital and  Paul  had surgery for his  ruptured appendicitis   .The doctor was angry that it was  almost  late .

”He prescribed some drugs for Ayo and asked me to pay for another drug , I didn’t tell him that I didn’t have but went back to where I went the previous night, mounted illegal  roadblock and  realized   20 Naira ,used it to buy drugs and  that was how he was saved .

”By and by my attitude towards life changed .I became a ”good” man to my boss for  whenever they bring any case to me I would charge the two  warring parties :the accused and the defendant  and collect  money from them .I would not settle  any   case without being offered money  .

THE BIG CURSE

”One day, I was broke and needed to entertain my  friends who would be visiting in the evening , since I had been used to the road block and known, I changed my style. I with two of my colleagues went to Agege  Pen Cinema as Traffic Wardens , we stopped an old man and checked all his papers which were all perfect in all sincerity . Since  there was no offence  to charge or accuse him of , we lied that his car tires were not  of the same product .The  old man came down and pleaded that  they were of same sizes but different make , we demanded 20 Naira or else he would go to the station.

“The fairly old man  begged us  and said that his son was sick and was taking him to the hospital .We ignored his pleadings ,  I went to the front of the car and wrote down the plate number and put it in my breast pocket. He   pleaded and later handed 20 Naira over to my colleague   after saying  some inaudible words  we couldn’t hear.

”After 30minutes the old man   left, my colleague  who collected the money  started laughing and dancing showing everybody the 20 Naira note. My colleague , would look at the money, laugh and run around showing everybody the money . At first I thought he was playing until he removed his clothes and started walking about naked till this day.

“For weeks I  became confused with what I saw. Later I summoned courage and said it  was his destiny . I was there and knew that   popular Police officer called Iya Toyin who was a no – nonsense Police  Traffic  Warden and  feared by all motorists in Lagos. Her story was known by many motorists in  Lagos.

”I remember a colleague of mine who collected bribe from a woman early  one fateful   morning , immediately the woman left my  colleague started climbing electric poles until he climbed one and went ahead to hold on to the wires, and the rest was history. Another officer kept on saluting electric poles anywhere he sighted them   till he died. I remember Inspector J who kept on dancing throughout his lifetime without drum .When I saw these I thought I  should refrain from collecting bribe but I had been used to it , my salary was no longer enough for me .I had no choice than to go back to road blocks.

THE BIG CRIME

”One day , two men approached me and asked me to cooperate and to look the other way  during their robbery operation. They gave me 50,000 Naira . Imagine how much it was then.

”Not quite 30 minutes I heard the sound of guns and saw smoke dancing towards heaven. I saw four  people on the ground , lay dead. I ran there to have a look, alas , one of them was my immediate younger brother who went to cash money from  the Bank. The robbers killed and made  away  with thousands of Naira  from the bank. For days I could not eat and could not tell anybody .Blood money!”.

”One day I was broke and needed money .I contacted a friend of mine who said he would assist me if I could keep the secret to myself .

MORE ATROCITIES

”Two days later this my friend came to see me in the office and told me there was a problem , he narrated how two fresh heads were found in his bag. He  confessed that he along with his friend beheaded two young men  for money making ritual. Before you say Jack Robinson , money had exchanged hands .I was given 50,000 Naira , and this money was distributed among my bosses and the rest as they say, is history. In fact  as if this was not enough, a woman was caught red handed for killing her husband ,first degree murder, but when she came with money , the rest again became history as usual.

”I was involved in many atrocities in my life .I knew a Pastor who was charged  for rape ,  an Imam was nabbed for gun running and  human rituals . A man who  was caught red handed  during robbery  was changed with another innocent  man in the night and was charged to court and sentenced to death while the original sinner was going about , walking free! 

”My sons don’t trust any police officer for they could set their parents up  because of money.

”One day I shot a Youth Corper  , a young graduate of engineering because he failed to give me five Naira I demanded from him .It was dead in the  night and he was the only one in the car, dead drunk. He exchanged hot words with me . After shooting him , I dragged his corpse  into  a nearby bush. Nobody saw  me or suspected me to date!

”The second day I went there and still saw the corpse but kept quiet.The case was reported that a dead body was sighted and I was asked to investigate it . Some of the  friends he once  quarreled with were arrested as suspects but after many  investigations by the  police, and court ….they were discharged and acquitted.

      SOURCE OF MY POWER

”There is no Babalawo, Alfaa and Spiritualists that I did not patronize  from Lagos, Ogun, Ondo, Oyo and Eastern states .I have one room full of juju,  in the four bedroom flat I built .There were  days I had to fast and must not sleep with  women. There were days I slept with mad women in Lagos and Ibadan  in the dead of the night and I would pretend to be  a mad man. There were days I had to go out naked  chanting incantations in the night in  market places . I had soaked myself in human blood for  hours and I had bathed using  twins’ placentas. I had shaved  many ladies and used their pubic hairs for rituals all to make sure I  was not killed or caught and  to cover  up my evil deeds. I had slept with dead bodies in the mortuary and gone to  the cemeteries in the dead of the night to receive power. I ate  the  tongue of a dead man raw!.

THE LAST STRAW

”The last straw  that broke the camel’s  back  and made me to  voluntarily resigned from the Police job was the one that jolted me most .

”One day I was alerted that some armed bandits were raiding some houses and a bank  .I called the Police station ( Division A) and we reinforced Mobile Policemen there .There was rain of bullets  on us as  we struggled to get some of the robbers , two were mowed down and four arrested  .The robbers’ strayed bullets had killed three people and a pregnant woman who tried to escape from their house to another safer place. The operation lasted two hours and we went back to our station. I slept at the station and the second day went back home. As I got to the entrance of my house I saw many people wailing and gnashing their teeth. I thought it was one of the family members of the victims. I went to relax in a beer parlour to cool down with a cold  bottle of beer before going back home. Here we discussed the operation that took place the previous night and how we fired the robbers and arrested four of them while four of them escaped with  bullet wounds .

” Again my  cellular phone rang and it was emergency from  the office as I was instructed to join some Mobile policemen to arrest some suspects with bullet wounds at an hospital .We got to the hospital and saw  four of the suspects with bullet wounds.

”The suspects were arrested and thrown into a waiting van.Two of the suspects were my two friends that I entertained the previous week. One of them  borrowed my uniform after  paying  20,000 Naira .That was why I had been using one uniform for two weeks .

”While in  the van they behaved maturely  as they didn’t look at me but only saying ‘Don’t worry, don’t kill us , you  are  safe’ .As I wanted to silence them with my gun  and report  later that they were trying to escape , they laughed and said ‘Just don’t worry , hold your peace, you all are in safe hands , don’t shoot’.

”At the Police station they made  statement and did not reveal where they got guns and ammunition including uniform despite being  tortured. 

”At the station I was informed that my family had been hospitalized  and should come home .When I got home the news was broken that my pregnant wife ( I married after the death of my first wife)was killed by  armed  robbers  who raided the area the previous night. I  was dejected and lost control of myself .The case was reported at the police station while their corpses were dumped at the mortuary .

NOW THE MESS

”In the evening when the robbers  wanted to eat one of them asked me to summon courage and put  rat poison into their food . I thought of it  and  knew the implication .  I said ‘No’. They assured me they would not   implicate me .

”The third day some  notorious armed robbers colluded with some policemen came to the station with sophisticated weapons , killed some police officers and freed the suspects.

“I  went to bury my wife, and two children . I was no longer comfortable in the uniform .I told some of my colleagues that my health was not good as I had acute hypertension, diabetes , heart disease and  ulcer, and  I  took  medical report from a doctor .I resigned after serving for 16 years .I relocated to another  state in far north in Zamfara State where nobody knows my story. I have spent  26years here now. Yes, I can speak Hausa very well and I am Seriki .I married an Hausa lady  and that is  your mother who bore me two kids  and that is  the two of you.

”Please my sons  all these nightmares are haunting me. There was a time I used to have strange dreams, I used to see strange faces of those I  killed. I abandoned my house in Lagos and nobody ever dreamt to go there yet nobody knows where I am .’Thou shall not kill’ but I have soaked my hands in blood. Now I am running about as the so Boko Haram are raiding everywhere and killing. I cannot go back to my hometown again for nobody knew where I am since I left over 26years ago. If I die please bury me here .You can imagine why I  didn’t use cell phone and use facebook or any social media for I know I could be spotted one day.

”I have been to many churches  to confess my sins and begged for forgiveness. But will God forgive  me ? ” he asked without an answer.

As his knees , feet, and hands turned mottled bluish-purple and his breathing was no longer normal cum with his irregular heart beat yet he was restless. He started twitching for some minutes, then suddenly gave a loud cry and then  became still and  cold. 

The two sons wept profusely realizing their father had soiled his hands in blood. They quietly buried their father without inviting anybody.

This  story is fiction